Are You Searching TMP – Oluwa (feat. Mohbad) Lyrics? You can read &Sing TMP – Oluwa (feat. Mohbad) Lyrics here. More than 10m Song Lyrics Available. Search Now…
TMP – Oluwa (feat. Mohbad) Lyrics
TMP
Oh lord of mercy Paranranrara Imole Oluwa jowo o, Oluwa 3ce Oluwa sign soro me o (oluwa sign soro me o) Oluwa dakun se temi funmi Oluwa gbo adura me o (Oluwa gbo adura me o) Baba so n gbohun me o Oluwa bless hustle me o (Oluwa bless hustle me) Oluwa dakun maje n lo lofo Igba wo ni ire ma kan me o (Igba wo ni ire ma kan me o) Baba so n gbohun me o Oh oh oh baba ti ba mi se Oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo Ki n lo ma jubilate, yea yea Baba ti ba mi se Oni ki n ma lo, ki n ma lo, ki n ma lo Ki n lo ma celebrate, yea yea Ko si ewu funwa, omo Olorun lawa E o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo Adura wa Ko le doju ti awa Aiymoye pains ti mo go thru Aiymoye dreams ti mo chase ti ko come true Aiymoye emi nicca se to de ti sonu Base on say won fe pa owo yi se won de fe hustle Mo bere orin kiko layi si eni to mo mi Aiymoye rap battle ti molo to je pe won na mi Ere lo pe abi woh no be small story (small story) Sugbon today me i give God the big glory (the glory) Aiymoye oro werray to ti so leyin me Sugbon nisiyin wo so pe awon fe feature me Elo lo wa nle won so pe no money Ti o ba ti si ooo wa ma lole bye bye Ko si ewu funwa, omo Olorun lawa E o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo Adura wa Ko le doju ti awa Oh oh oh baba ti ba mi se Oni ki n ma lo, ki n ma lo, ki n ma lo Ki n lo ma jubilate, yea yea Baba ti ba mi se Oni ki n ma lo, ki n ma lo, ki n ma lo Ki n lo ma celebrate, yea yea Baba lo ni ki n ma lo... eh Owun lo ni ki n ma lo... Ko ma de si ewu lono Baba lo ni ki n ma lo ooo Owun lo ni ki n ma lo Ki n somo lo, ki n gbomo lo Nine Aye Imole Ko ma de si ewu lono