Are You Searching Bukiemma – Hymn 176 Baba Palase Lyrics? You can read &Sing Bukiemma – Hymn 176 Baba Palase Lyrics here. More than 10m Song Lyrics Available. Search Now…
Bukiemma – Hymn 176 Baba Palase Lyrics
Bukiemma
Baba pa laşe lat’Ọrun wa Ki gbogbo aiye si wariri Fun ‘Jọ Mimọ, lat’Ọrun wa Ijọ yi ni, yio wẹ aiye mọ Ajẹ oşo, yio wariri L’abẹ agbara Mimọ yi Awọn Angẹli si kun f’ayọ Iyanu, f’ọkọ ikẹhin Halleluyah fun işẹ Oluwa Igba ikẹhin na ti de Kristi Jesu yio pada wa Lati wa şe ‘dajọ aiye Iku Rẹ lori agbelebu Ẹjẹ ati omi to nşan Kuro ninu iha Mimọ Rẹ Ko gbọdọ lo sori asan Gbogbo oju yio si tun ri Pẹlu awọn Angẹli Mimọ Rẹ Kẹlẹşẹ ronupiwada F’ọjọ iwariri nla na Awọn Angẹli yio fun ipe A o ka ilẹ at’Ọrun Okun yio d’ohun airi mọ Awọn oku yio ji dide Imiran pẹlu ayọ nla Imiran pẹlu ijiya Elẹşẹ yio wariri lọjọ na Awọn ‘toku f’ọrọ Kristi Awọn t’o ru Agbelebu Rẹ Nwọn yio ji pẹlu ogo nla A o wọ wọn laşọ ogo, A ode wọn lade wura, Mariwo ọpẹ lọwọ wọn, Nwọn yio fo pade Kristi, Arẹ ki yio si fun wọn mọ, Halleluyah l’ohun orin wọn Halleluyah oo oooh Halleluyah l’ohun orin wọn Halleluyah l’ohun orin wọn
